Esè Odò

Francois xavier BOSSARD, Motunrayo OROBIYI, Nicolas GIRAUD

Ìpè tó dun bá wa lójijì
Eni tó bá ló lè ròhin rè
Tony cllen ti sípò padà
Sùgbón títí láé nìrántíì re yóó wà

Smile on you are celebrated
Shine on, shine on you are a star

Smile on you are celebrated
Smile on, smile on you've done us proud

O Ò ódigbéré o, ódàrìnnàkò

Ó doju àlá o - erínwó

O dewurée jeléjelé

O dàgùtàn-an jemòjemò

O daláàmu tíí je légbèé ògiri

O dàgbàrá òjò - oò yalémó

Ìpàdé desè odò - ó dòhun oo

Smile on you are celebrated
Shine on, shine on you are a star

Ká tóó rérin - ó digbó
Ká tóó réfòn - ó dòdàn o

Héè Diípò gbáyé o - ó seeni ire
Tony cllen ó dòrun-un 're
O gbá'yé o - o hùwàa're
Tony cllen ó dòrun-un 're
Háà ó dòhun o - ó desè odò
Tony cllen ó dòrun-un 're

Ìpéjopò ìdùnnu lafi rántíì re
Tony cllen ó dòrun-un 're

cya, omo àtomoo'mo wón gbèyìn-ìn re
Tony cllen ó dòrun-un 're
Isé tóo se sílè kòlè bàjé láé
Tony cllen ó dòrun-un 're
Ebí, ará , òré o wón sèdáròò 're
Tony cllen ó dòrun-un 're
Àjoyò dídùn ni lafi sè 'dáròò re
Tony cllen ó dòrun-un 're

Beliebteste Lieder von Fixi

Andere Künstler von Film score