Adedotun

Brymo

Verse 1
Awon adan fo loke
Wan foka si oju Orun
Wan o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é Oré o
O wun o n wa
O wa ni waju re

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............

Verse 2
Awon adan fo loke
Ni igba igba
Won ku oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho wan
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo sokoto
O wa lapo Sokoto

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............
(X2)

Ko pamo si é
Oré o
Owun o n wa
O wa ni waju re
Ore o........

Wissenswertes über das Lied Adedotun von Brymo

Wann wurde das Lied “Adedotun” von Brymo veröffentlicht?
Das Lied Adedotun wurde im Jahr 2020, auf dem Album “Yellow” veröffentlicht.

Beliebteste Lieder von Brymo

Andere Künstler von