Okunkun
Brymo
N ò fara pamọ' fún ẹ òló mi
Èé ṣe t'ọ'rọ' rẹ sá ń fún mi
N ò ṣ'olùgbàlà
Òótọ' ló dùn mo wárí o
Káwọn ọ'rẹ' mi lè kó mi yọ lódodo
Ìfẹ' nìkan ló kù fún mi
Kò s'ẹnìkan tó lè kó mi yọ
Àjò layé
N ò mọ bí mo ṣe wá o
Mo fura pé ibẹ' ni mò ń lọ
Òkùnkùn lati wá
Òkùnkùn là ń lọ