Temi Ni Temi
Ife mi dariji mi
Omode n se mi
Afarawe o se temi
Ka daduro ni mo wari
Moti so tele tele ri
Igboro o ma rerin ri
Ijakadi lo mu nise
Karohunwi o bopo sise
Bi nba fa wa n'ole
Bi nba tule wan'loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere
Aba lo aba bo
B'ohun won ko para won oh
Ohun a ni la n nani
Temi ni temi
Awelewa forijimi
Mo lakaka kin to de bi
Riro mede o se temi
Nibi lile la n b'okunrin
Ife re sha lo'n duro timi
O dudu, o funfun, o pupa
Ife re sha lo'n munu tumi
Ninu erun at'ojo at:ilera
Bi nba fa wa n'ole
Bi nba tule wan'loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere
Aba lo aba bo
B'ohun won ko para won oh
Ohun a ni la n nani
Temi ni temi
Aba lo aba bo
Temi loje lale eni oh
Gbogbo igba ti o ba lo
Mo mo pe o pada wa